
Lokunrin, at lobinrin
Baba wa Bola Ahmed Tinubu lo ni kin so fun gbogbo awa Omo ipinle Ondo state, will katu yaya tuya sita lodibo Lola tin se ojo abameta (Ola) ojo kerindinlogun osun kookonla odun egberun meji ati ooko le merin (16/11/2024), fun Baba wa, egbon wa, Aburo wa, Omo wa tin se Olorire Omo Aiyedatiwa, ni Abe egbe APC.
AKU ORIRE P GBOGBO OMO IPINLE ONDO.
AIYEDATIWA DE, IRORUN DE
Akede ni.
Omoyin Mebinone Asogbon.
Omo Asogbon Agie ni ibile Ilaje, ilu Atijere.